Lyrics: Kay wonder ft Mike Abdul Jesu

Kay wonder ft Mike Abdul JESU Lyrics
Ina nla ti o se ngbamu
 Ako ma ti ika Lehin
 Oba ti mo gbojule
 Kokoro ohun gbogbo
 Eyin l’orin l’enu mi
 Eyin l’ayo okan mi
 Eyin l’ohun gbogbo ti moni ti mo fi nsako o
 .
 Chorus… Jesu…..
 Haaaa…..Jesu…….
 Pe Jesu yi ko ri iyanu….Jesu….
 Haaaaa…… Jesu.
 .
 .
 Verse…
 E pee loruko to nje o,
 Oba Awon oba,
 alagbara, Olorun mi to ga,
 akoni mi, asuwaju Ogun,
 ibere ogun, o kehin ogun,
 gbogbo ara kiki ija,
 owo Odi Jericho lai lo katakata,
 Gbogbo ara kiki ija
 owo odi Jericho lai lo katakata,
 Eyin lorin lenu mi
 Eyin layo okan mi,
 Eyin lohun gbogbo ti mo ni ti mo fin sako o Jesu
 .
Chorus… Jesu…..
 Haaaa…..Jesu…….
 (Oba to wole iku, to nwole aru)….Jesu….
 (Jesu loni Central Bank)….. Jesu
 (Agan ti ko ribi o fun ni Omo)….Jesu….
 Haaaaa…
 .
 .
 Verse 3,
 (Mike Abdul)
 E pe loruko to nje
 Lo ba tan o, loba tan o, call on Jesu Lobatan,
 pariwo o, pariwo,
 Testimony Je ko mo, lowo kan, lowo kan,
 ire ayo mi wole de,
 lenu ope mi o gbolude,
 alert yen wole,
 I will send alert to Heaven Hallelujah o
 Hallelujah my song
 Jesu my Logo,
 .
 .
 Verse 3.
 E pe loruko to nje o,
 Aribiti, ribiti, Aribiti Aribiti rabata,
 Arabata, ribiti, Aribiti Aribiti Aribiti,
 (You are the Eze Nalelu Ogodo yanapulana)…2x
 Eyin l’orin l’enu mi,
 Eyin l’ayo okan mi,
 Eyin lohun gbogbo ti mo ni ti mo fi nsako o …Jesu
 .
 .
 Bridge.
 (Eyin ni Gbani gbani gbani gbani gbani gbani to Aye nsaya)2x
 .
 (Ate rere Kari kari Kari Kari Kari gbogbo aye)2x
 .
 (Ojo mini mini mini mini mini
 ti nje ara o de ni)2x
 .
 Eyin lorin lenu mi, Eyin layo okan mi, Eyin lohun gbogbo ti moni ti mo fi nsako o Jesu.

 
 





