All Gospel MusicAll Nigerian Gospel MusicLyrics
Download Music:: Oro Ogo – Sunny Ola @Sunnyolamusic @AllBazeRadio
Sunday Olabode Popularly known as Sunny Ola, Fantastic has finally released Him Anticipated single titled “ Oro Ogo”
[download id=”1956″]ORO OGOPsalmsAwon orun nsoro ogo Olorun ati ofurufu nfi ise owo re hanOjo de ojo nfohun, oru de oru nfi imo han, ko si ibikan tabi ede kan nibiti a ko gbo iro woniro won la aiye ja ati oro won de opin ile aiyeeeeChorus: Gbogbo won lo ri gbogbo won lo moGbogbo won lo nso, oro ogo re,Gbogbo won lo ri gbogbo won lo nsoGbogbo won lo mo titobi ogo re.Solo 1.Orun, osupa, irawo, imole,gbogbo aiye a won orun omi to nbe loke orun/2×Gbogbo won pata lo ti gba, gbogbo won lo mo siGbogbo won lo ti gbo o, ohun OlagutanChorus….Solo 2.Gbogbo ekun won nwole, gbogbo ahon won jewo,Ninu orun ati ni aye o, foba to logoKo sogun to le da o duro, ko sagbara to to bori re o,Gbogbo agbara, gbogbo ipa ooo won gbo ohun re.Solo 3.Oke nla fooo, okun ri o o sa,jodani ri o o pada sehin, oke kekeke ko le duroCall: mo foribale foba to logoResp: Mo foribale foba to logo /2×Call: ki lo se Iwo okun ti Iwo fi sa? Ati iwo jodani ti iwo fi pada sehinEhin oke nla ti e fi nfo bi agbo ati ehin oke kekeke bi odo agutanWon logo tawon ri koja riri, won logo tawon ri koja afenu soWariri iwo ile o niwaju Olorun Israeli,eni to so apata di adagun omi, ati okuta ibon dorisun omi.Oluwa lo nile ati ekun re o