Adeyinka AlaseyoriAll Nigerian Gospel Music

Adeyinka Alaseyori – Ayemi Ladun Mp3 Download

Download Adeyinka Alaseyori - Ayemi Ladun

Nigerian gospel singer and preacher Adeyinka Alaseyori come give us another brand new song titled ”Ayemi Ladun”. start new month with this wonderful song.

this unique composition is a blockbuster that you should add to your playlist if you enjoy decent music.

Mp3 Download

Lyrics
Ayemi Ladun – Adeyinka Alaseyori

Aye to ti daru tele tele

lo fun ni tumo ooo

ile omo to ti doku soji

iyanu to se lori si ri si lo je ka ye wa dun

oni se yanu iwo la wa gbe ga

igba ti kosi iran lowo iwo ni iranlowo wa

igba ti gbo gbo eniyan so pe oti tan iwo lo so pe oku

iyanu to se lo ri siri si lo je ki aye wa dun

ose ooo

tori ani e ni baba

aaaaaaa aye mi ladun oo aye min loyin

Tori mo ni o ni baba

Gbogbo ebe adura wa tele tele lo do testimony airina airilo wa di ohun igbagbe iranlowo anu, igbega ti mo ti lati Odo Owo re lo ti wa mo gba pe oooooo mo kan RI aanu gba ni Iyanu to mo ri kin se ogbon ori, kin se to iwa mimo mi rara, iwo lo mu mi lowo Dani rin irinajo Anu to GA oooo Mo gba pe mo kan RI anu gba ni

aaaaaaaaaa qye mi ladun oooo aye mi loyin Tori mo ni o ni baba

lojo ti mo ti mo ooo laye mi ti dun oo u have beautify me Anu nla ni mo ri ooo ki ni mo se ti mo fi ri anu eyi gba ooo iwo lo fe mi ni afe tan ti mo fi je oju lowo omo re

Related Articles

Leave a Reply

Back to top button