Lyrics

EDUNSIN Lyrics by Kay Wonder

EDUNSIN Lyrics

 

Chorus-

E dun si, E dun bo,

Mimo ni yin JESU,

Mumi pe ninu ife re,

Ki ma se so Ile ogo nu,/2ce

 

 

Verse 1,

Ngo ma rin ninu ife yin,

Ngo ma yan fanda ninu iberu re,

Ohun aye yi ko ma ba orun mi jee

Ki n mase so Ile ogo nu,

.

Oro re ni mo pa mo ni Okan mi,

Ki emi ki o ma ba se si o,

Gbogbo iwa Ese,

irin Ese, oro ese to fe de mi lona,

Jesu gbaa lowo mi

mumi pe ninu ife re.

.

.

Verse 2,

Kini yio ya mi ninu ife JESU?

Se iwa eeri ni? Se Agbare ni?

Jesu mo wa tiletile mi,

We ninu ibu Eje re,

.

Mumi pe ninu ife yin,

Mumi yee fun Ile ogo,

Ki ohun ÒSÓ aye yi ma ba orun mi je,

Mumi pe ninu ife re,

 

 

Hymn- Ninu irin Ajo mi, Beni mo nko rin, mo ntoka si Calvary si ibi eje na,

Iran wo lo de ninu l’ota gbe dide, Jesu lo n to mi lo Isegun daaju………

 

Coda- Sebi iwo la mo ikoko

Aye mi o, Oluwa momi, moo mi boo se fe/2ce bi o ba mo mi, ma ri bi o se fe, bi o ba mo mi, aye mi a dun wo, Sebi iwo la mo ikoko aye mi o, Oluwa momi mi, mo mi Bo se fe…

.

* Ohun k’ohun ti yio de mi lona iye

Metalokan Baami mu kuro

YouTube video

Related Articles

Leave a Reply

Check Also
Close
Back to top button