All Nigerian Gospel MusicLyrics
Trending

Kay Wonder Asoro Se Lyrics 

ASORO SE Lyrics

Intro-

Your words are Yes and Amen,

Your words are pure and true,

What you have spoken yesterday,

It has come to pass today,

ASÒRÒ matase, Ese o a soro Maye,

Ese ooo, ASÒRÒ SE,

.

Chorus- Asoro Se a pe e se,

Asoro se, a pe e se o,

Eyiti e wi Lana, o ma ti se loni,

Asoro se e ma se o baba,

.

Verse 1. Gbogbo ileri re duro, o duro o Lailai, oro ti e ba so,

yi o se, yio se o,

asoro matase, Ese o, asoro maye,

Ese ooo, asoro se, Awon orun le fo lo, sugbon ohun kiun kiun ti e ba so, Gbogbo ileri ti e ba se, yi o se,

.

Verse-2,

Eyin lele se, ohun t’aye ko le se,

Eyin lele tu ohun ti satani ti de,

Aiyipada, to le yi ohun Gbogbo pada,

E to be o, eju bee lo,

.

*Eyin lele si, Ile omo t’aye ti ti,

Eyin lele ja sekeseke t’aye ti fi de eniyan,

Eyin t’e mu ketekete Balaamu f’ohun bi eniyan, e to bee, eju bee lo,

 

*Oke nla nla, oke wewe

Iji lile, ko le duro niwaju re,

Olorun e ti to bi to o,

Etobi Oluwa

 

Chorus- Asoro se, a pe Ese, Asoro se a pe e se o, eyi ti e wi Lana, o ma ti se loni, a soro se e ma see o baba.

 

Hymn • Ninu irin ajo mi,

bee ni mo nkorin

Mo ntoka si Kanfari,

si ibi eje na,

Idanwo lo de ninu l’ota gbe dide

JESU lo n to mi lo, isegun daju,

 

……. Haaa mo fe ri Jesu,

ki ma wo oju re

Ki ma korin titi ni pa ore,

ninu ogo ni ki ngbohun soke,

pe mo Bo, ija tan, mo de Ile mi….

.

Hymn 2. Olugbala

gbohun mi, gbohun mi, gbohun mi,

Mo wa so do re gbaami,

ni ibi agbelebu,

—Oluwa jo, gbaami, nki yio, bi o ninu mo,

Alabukun gba mi, nibi agbelebu.

.

CODA-

ki le o le se, ta le o ju lo,

alagbada ina,

you are the great and mighty God/2x

.

CODA 2-

Babiloni Babiloni ti wo

Babiloni wooooooo

Download Mp3

Related Articles

Leave a Reply

Back to top button