All Nigerian Gospel Music

Jaybest – Lese re ft Princess Ifemide (Prod by Gbenga Emmanuel)

Seasoned and Anointed gospel music minister,Jaybest releases a brand
 new spirit-filled sound  titled  “Lese re” Featured  Gbenga Emmanuel

Download

Jaybest – Lese re Lyrics 

re,Lawo le(mo dohun Mi po mo tiwon)

Lese re,La retina(Awon ti iro won layeja)
Oba toga,to lagbara o(hmmmmm)
Oba topo ni ore(okan mi soro Orin tori mi ole ko)
Lese re,Lawo le(kabiesi ko she pa ko se to loye,oba angeli oba eniyan)
Lese re,La teriba
Oba toga,to lambada o
Oba topo ni ore
Egbe ori yin soke,eyin enu ona
Ki a jumo gbe yin soke eyin ilekun aiyeraye
Ki oba ogo ko wo inu ile wa
Tani oba ogo yi oo?
Oba to le,to le ni Ogun
Imole ninu gbogbo aiye ooo
Owawa wowo olodumare
Ragajigan eni MImo Israeli
Dondo dawa eni MImo israeli
Agbo ma ti ooo
Eni ti Ina aiye o me mu
Olorun ti ki sun to kuni lorun ooo
Talo to gbe ina koju re,mi o tori
Olurogbe gbogbo aiye
Tani ale fi o we ni gbogbo aiye o
Tani ale fi owe ni gbogbo orun o
Aw on agbagba merinlelogun gbogbo won woke nibi esere
Awon agbagba merinlelogun gbogbo won nke mimo
Mimo mimo oo,MImo olori Ogun
Mimo mimo o,mimo eni mimo julo
Mimo MImo oo,olurogbe gbogbo aiye o
Mimo Mimo oo,okan paya awon olote
Mimo MImo oo,Awole fun oo
Otomi se ibi isadi
Mowole feni mimo jump
Otomi gbaye,otomi rorun kedere,otomi rin lori satani
Owawa wowo olodumare
Ina nla ooo
Emi nke MImo,MImo,mimo,olori ogun

Related Articles

Leave a Reply

Back to top button